ORI-ORO : LSUS
ÒSÈ KESAN AN
ORI-ORO
AROKO ALAPEJUWE
ITESIWAJU LORI AROKO ALAPEJUWE
ÀKÓÓNÚ
- BI AROKO WA SE GBODO RI
- SISE ILAPA ERO
- BI A SE N SE ILAPA ERO
Aroko je ona ti a ngba gbe ero eni kale lori koko tabi ori oro kan fun elomiran lati gbe e yewo.
Aroko alapejuwe ni aroko ti a n fi n se apejuwe nnkan tabi enikan. Bi a ba fe ko aroko, a gbodo ni imo kikun lori ohun ti a nse apejuwe re, tabi ori oro ti a ba yan. O si le je ohun ti a ni iriri nipa re.
A gbodo se apejuwe yii lona ti eni ti o n ka aroko naa yoo fi le maa foju inu wo ohun ti a n sapejuwe re tabi ki o tile da nnkan naa mo.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.