Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

AKAYE 1

ClassNotes Team 6 MIN READUPDATED 1 JUL 2026

 

OSE KEJE

AKAYE 1

(Ka akaye yii ki o si dahun ibeere ti o tele)

Ojo ko ti awon eegun yoo pidan ni ita Oba. Oba ati awon ijoye ati gbogbo awon ero ti pese wamuwamu si aaye won. Bee ni olukuluku awon eegun nla n ta okiti, won le awon eegun keekeeeke lese wa si ojude Oba. Ariwo n ta gee bee ni kaluku ti n lo juba niwaju Oba ki won to lo jokoo laaye won. Eyi ti o ba de keyin a si juba awon ti o ba niwaju ki o to jokoo. Sugbon okan ganta bayi de, se ni o lo jokoo ni tire leyin ti o ti ki Oba tan, ko tile naani awon…