AKAYE,
OSE KEFA
AKAYE
akaye ni ohun ti a ka ti o si ye wa yekeyeke. Ti a ba fe dahun ibeere ti o tele akaye, a gbodo fi ara bale daadaa ka akaye, a gbodo ka akaye ni eemeji. Leyin eyi ni o wo awon ibi ti ibeere ti jeyo ninu akaye. Leyi ni yoo dahun ibeere. Ti o ba ti dahun ibeere tan ni yoo tun wo boya idahun ba ibeere mu.
Ka ayoka isale yii ki o si dahun ibeere ti o tele e.
Owo se pataki, o se koko. Bi o tile je pe owo ko fe ki enikeni damoran kanakan leyin
ohun, sibe a gbodo mo pe iranse lo je. Ko ye ki o di oga…