Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

AKAYE ONISOROGBESI

ClassNotes Team 3 MIN READUPDATED 1 JUL 2026

OSE KEJO

AKAYE ONISOROGBESI                                                              

( Olu ati Aina pade arawon ni ile itura piremia ni Ilu Ibadan. Won ti ri arawon tipe die. Bayi ni won bere oro won.)

Aina   Olu, iwo niyen, e ma ku ojo meta.

0lu     Emi niyen o, lowo oko aaro.

Aina   Se ko si nnkan Olu? O da bi igba wi pe ara re fa die.

Olu     Ara mi da ko si nnkan to n se omo olorun. Bi ode ti ri naa ku ni.

Aina   Iyen o maa to o ro. Arun gbogbo aye niyen ( Leyin igba ti won joko ).

Olu     Aina, Iyawo ati awon omo nko?

Aina   Gbogbo won wa daadaa. Igba ti mo tile n bo ni oko…