Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

AROKO ASOTAN/ONIROYIN,

ClassNotes Team 7 MIN READUPDATED 1 JUL 2026

OSE KARUN-UN

AROKO ASOTAN/ONIROYIN        

AKOONU:

  • Itumo
  • Apeere.
  • Igbese.

     Aroko ni ohun ti a ko sile lati inu arojinle wa fun elomiran lati ka a. Orisiirisii aroko lo wa, a ni aroko oniroyin, onileta, alalaye, onisorogbesi, alapejuwe, alariyanjiyan.

Aroko oniroyin: ni a n pe ni aroko asotan.  Iru aroko yii ni a ti maa n so itan isele ti a fi oju ri tabi eyi ti a kopa ninu re, tabi ti a gbo lati enu enikan. Aroko yii maa n so nipa ohun to ti sele seyin ni.  Die ninu awon ori oro ti a le ko aroko oniroyin le lori ni wonyi:-

  1. Ija igboro kan to soju mi
  2. Ijamba moto kan ti mo wa ninu re
  3. Ojo kan…