SubjectPaid lesson
AROKO ALALAYE KIKO AROKO ALALAYE (APEERE)
CT
ClassNotes Team 3 MIN READUPDATED 13 JUN 2026OSE KARUN-UN
AROKO ALALAYE KIKO AROKO ALALAYE (APEERE)
ISE TI MO FE SE LOJO IWAJU
Iru ise wo ni o fe se lojo iwaju
Alaye lekunrere lori ise naa
Idi ti ise naa fi wu o
Iru ipo wo ni ise yii le gbe o de
Ero re lori ise yii.
EBA TITE
Iru ounje wo ni eba?
Ibo ni eba yii ti wopo?
Bawo ni won se n te eba ( alaye ekunrere)
Ki ni o fa ti o fi feran eba?
Iru ise wo ni eba n se lara.
IGBELEWON
- Ko aroko lori “ ise ti o fe se lojo iwaju”
- Ko aroko lori “ eba tiite
IWE AKATILEWA
Adewoyin S.Y (2004) New simplified Yoruba L1 iwe keta…