IYATO TO WA LAARIN APOLA ATI AWE GBOLOHUN
OSE KETA
IYATO TO WA LAARIN APOLA ATI AWE GBOLOHUN
Awe gbolohun ; - Laisi gbolohun, ko le si awe gbolohun rara. Ara gbolohun ni a ti fa awe gbolohun yo. Gbolohun eleyo oro ise a maa je olori awe gbolohun, nitori wi pe eyo oro ise kan ni o wa ninu re ti ko si gun gbooro. Sugbon ninu gbolohun olopo oro ise tabi gbolohun alakanpo ni a ti maa n ri awe gbolohun afarahe.
Awe gbolohun afarahe je eyo oro tabi akojopo oro ti ko le da duro funrare laisi olori awe gbolohun. Awe gbolohun afarahe le je:-
i.awe gbolohun afarahe asaponle.
ii. awe gbolohun afarahe asodoruko.
iii. awe gbolohun afarahe asapejuwe.
AKIYESI;-Odidi gbolohun leyin pe…