Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

ORO APONLE.

ClassNotes Team 1 MIN READUPDATED 5 JUL 2026

OSE KESAN-AN

ORO APONLE

Oro aponle (adverb): Oro aponle ni a fi n pon oro-ise le ninu gbolohun. Ni opo igba a maa n ba won ni iwaju oro ise ninu gbolohun ni. Bi apeere:

          Igi ope naa ga fiofio

          Oko naa run womuwomu

Ata naa pon wee

Olu sare tete

IGBELEWON

  1. fa ila si idi oro aponle ninu awon gbolohun wonyi

Omo naa fo feere

Ise yii le jojo

O n jeun waduwadu

Iwe naa ya perepere.

AKATILEWA

  1. Oyebamiji Mustapha (2002) Eko ede Yoruba titun Iwe keji (J.S.S.3) oju iwe 1-4 University Press Plc.
  2. S.Y Adewoyin (2004) New simplified Yoruba L1 iwe keta oju ewe 1-5 Copromutt (publishers) Nigeria Limited.