ORI-ORO AKOTO EDE YORUBA
OSE KEJE
ORI-ORO AKOTO EDE YORUBA
ITAN BI EDE YORUBA SE DI KIKO SILE
AKOONU
Ki owo eru to bere ni iwo oorun Afirika,asa iwe kika sajeji ni ile Yoruba,a kan n so ede Yoruba lenu lasan ni,ko si akosile.
Nigba ti owo eru bere opolopo omo Yoruba ni awon onisowo alawo funfun ko leru lo si ilu won.
Leyin opolopo odun ni won fi opin si owo eru yii gbogbo awon ti won ko leru ni won so di ominira ni ile saro(Freetown) ti won si bere igbe aye titun.
Leyin opin owo eru yii ajosepo si n tesiwaju laarin iwo oorun pelu awon alawo funfun ,won wa ra ohun elo fun ile-ise okowo won.Laarin akokoyii, awon…