ORI-ORO- APEJUWE IRO FAWELI
OSE KETA
ORI-ORO- APEJUWE IRO FAWELI
ORIKI,ABUDA
IDAKO
ATE FAWELI
AKOONU
Iro faweli-;ni iro ti a pe nigba ti ko si idiwo fun eemi ti o n ti inu edofooro bo. ORISII
Ona meji ni iro faweli pin si
Faweli airanmupe
Faweli aranmupe
Abuda fun isapejuwe iro faweli
Eyi ni abuda ti a n lo fun isapejuwe iro faweli
Ipo ti ahon wa
Ipo ti ete wa
Ipo ti afase wa
Ipo ti apa to gbe soke ga de ninu enu.
ABUDA
Ipo ti ahon wa-;bi a ba tele abuda yii,ona meta ni a le pin iro faweli si,nitori pe ona meta ni ahon wa pin si,ipo…