Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

ORI-ORO ILANA ATI OGBON TI A N TA FUN AROKO KIKO

ClassNotes Team 4 MIN READUPDATED 13 JUN 2026

OSE KEJO

ORI-ORO    ILANA ATI OGBON TI A N TA FUN AROKO KIKO

AKOONU

          Itumo,

Orisiirisii Aroko

          Aroko je ona ti a fi n mu eniyan ronu lori koko oro kan,ki o si ko ero re sile laifi atamo-mo-atamo..

          ORISIIRISII AROKO.

Orisiirisii Aroko ni o wa ninu ede Yoruba,awon naa ni : -

          Aroko oniroyin / asotan.

          Aroko alapejuwe

          Aroko onisorongbesi

          Aroko ajemo-isipaya

          Aroko alarinyanjiyan

          Aroko leta kiko.

EROJA PATAKI FUN AROKO KIKO.

Eyi ni awon ohun ti o gbodo je akekoo logun,ti yoo fii je ki o le gbe aroko ti o gbamuse kale.

  • Yiyan ori oro: - Akekoo gbodo yan ori-oro ti o ba mo nipa re daadaa.