Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

APOLA – ORUKO

ClassNotes Team 4 MIN READUPDATED 5 JUL 2026

OSE KETA

APOLA – ORUKO

 

AKOONU

APOLA ORUKO:- Ni oro tabi akojopo oro to le duro gege bi Oluwa, abo pelu eyan tabi laisi eyan ninu gbolohun. Apeere:

 

Ile  wo

O wa

Awa naa  je  eba metameta.

 

IHUN APOLA ORUKO

Apola – oruko le je eyikeyii  ninu awon wonyi

Oro-oruko kan soso pere

Oro aropo-oruko

Oro aropo-afarajoruko

Oro – oruko pelu eyan

Oro- oruko pelu awe gbolohun

 

1. Apola-oruko to je oro-oruko kansoso pere. Ap:

Bade se wahala.

Aja pa okete.

Mama  fo aso.

 

2. Apola-oruko to je oro aropo-oruko. Ap:

Won sun

Mo  ko leta

E gbin in

 

3. Apola-oruko to je oro aropo afarajoruko. Ap:

Oun ni ore mi