AWON ISORI GBOLOHUN YORUBA GEGE BI ISE WON..
OSE KESAN-AN
AWON ISORI GBOLOHUN YORUBA GEGE BI ISE WON.
Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí won ń se. Àpẹẹrẹ:
Bólú je èbà
Bàbá kọ ebè
Èyà gbólóhùn. Orisiirisii ni awon eya gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba.
Gbólóhùn Eleyo oro-ise
Gbólóhùn Olopo oro-ise
Gbólóhùn Ibeere
Gbólóhùn Ase
Gbólóhùn Alaye
Gbólóhùn Akiyesi alatenumo
Gbólóhùn Kan
Gbólóhùn lyisodi
Gbólóhùn Asodoruko
Gbólóhùn Eleyo Oro-Ise-: ni gbolohun ti o maa n ni eyo oro ise kan
Apola oro oruko ati apola oro ise ni o maa n wa ninu gbolohun eleyo oro-lse.…