Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

IPAROJE/IPAROJE

ClassNotes Team 5 MIN READUPDATED 12 JUL 2026

OSE KEJO

IPAROJE/IPAROJE

 

AKOONU

Iparoje:  ni fifo awon iro tabi siso awon iro nu nigba ti a ba n yara soro. Ti a ba n yara soro, a maa n pa awon iro kan je, awon iro ti a maa n paje ni:

  • Iro konsonanti
  • Faweli ati ohun
  • Apapo konsonanti, fawli ati ohun ninu oro

 

Nibi ti a ba ti pa iro je, alafo yoo wa nibe, a o wa pa iro mejeeji po di eyokan.  Pipapo apa oro eyo kan ni a mo si isunki.

 

IPAROJE/ISUNKI

Se ise = S ( ‘ ) ise =  sise (faweli ‘e’ ni a paje)

Adiye = adi (   ) e    adie (kons y ni a  paje)

 

IPAJE…