Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

ISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISE.

ClassNotes Team 2 MIN READUPDATED 5 JUL 2026

OSE KERIN

ISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISE

 

AKOONU

Gbolohun Olopo Oro- ise ni gbolohun ti o maa n ni ju oro-ise kan lo, o le je meji meta tabi ju bee lo. Gbolohun olopo oro-ise naa ni a mo si gbolohun onibo. Apeere:

Mo jeun mo si yo.

Won wo aso, won si wo bata.

Won n rin, won n yan, won si n se oge.

 

ORISIIRISII GBOLOHUN OLOPO ORO-ISE

Gbolohun olopo oro-ise alakanpo

Gbolohun olopo oro-ise afibo

Gbolohun olopo oro-ise afipase

Gbolohun olopo oro-ise asinpo

 

GBOLOHUN OLOPO ORO-ISE/ ALAKANPO:  a ma n lo awon oro-asopo kan lati so gbolohun eleyo oro-ise po di gbolohun olopo oro-ise akanpo. Awon oro-asopo naa ni sugbon, si bee. Apeere:

 

Ade