SubjectPaid lesson
LETA KIKO.
CT
ClassNotes Team 6 MIN READUPDATED 5 JUL 2026OSE KEWAA
LETA KIKO
AKOONU
Orisii leta meji lo wa ninu ede Yoruba, awon naa ni; -
Leta gbefe ati
Leta aigbagbefe.
Leta mejeeji ni o ni eto ati ilana ti a n gba ko won.
LETA GBEFE: ni leta ti a ko si obi, ara, ore, ebi, egbon, aburo tabi si eni ti a mo ri. Ilana leta gbefe ni:
- kiko adiresi eni ti o ko leta eyi le je olooro tabi elebe. Ni owo otun oke leta ni o maa n wa.
- Deeti
- Ibere leta pelu ikini ibere. Apeere: Tunji mi tooto, Aunti mi, Baba mi owon, Mama mi owon. Ikini ni o maa n bere leta. A le wi pe ‘Se alaafia ni o…