ORO-AGBASO : LSUS

OSE KEJE

ORO-AGBASO

 

AKOONU

Oro agbaso:- je siso oro ti a gbo lenu oloro fun elomiran. Iru oro tabi iroyin bee gbodo je eyi to ti koja. Oro agbaso le je ohun ti enikan so nipa wa tabi elomiran. O si le je iroyin ohun to sele nibikan. Oro agbaso naa ni a mo si afo agbaran. Awon wunren atoka oro agbaso ni: so, wi, ni, ki, pase, wi pe, salaye, so fun  abbl

Tunde ni oun ko ni wa si ipade.

Sola beere boya a ti jeun

Bi a ba n se agbaso, ayipada maa n de ba oro aropo oruko tabi oro aropo afarajoruko, ti eni to n soro ba lo oro aropo-oruko tabi oro aropo-afarajoruko enikinni ninu oro re – oro aropo –oruko tabi afarajoruko eniketa ni eni to n se agbaso yoo lo. Ap

Mo ri owo he.

Agbaso-        O ni oun ri owo.... View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.