AKOTO (ORISIRISI ORUKO) : LSUS
OSE KEWAA
AKOTO
ORISIRISI ORUKO
AKOONU:
- Oruko amutorunwa
- Oruko abiso
- Oruko abiku
- Oruko oriko
Oruko amutorunwa ni oruko eyi ti a n pe omo gege bi ona tabi ipo ti omo gba waye nigba ti won bi.
ORUKO ITUMO
Tiawo/Kehinde akobi ninu awon ibeji(aburo)
Kehinde omo ti a bi tele Taiwo
Idowu omo ti a bi tele awon ibeji
Ige omo ti o ba ese waye
Dada omo ti irun ori re ta koko
Ajayi omo ti o da oju bole nigba ti a bi
Oke omo ti o di ara re sinu apo felefele waye
Olugbodi omo ti ika owo re tabi ika ese re.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.