EYA AWE GBOLOHUN AFARAHE : LSUS
OSE KERIN
EYA AWE GBOLOHUN AFARAHE
AKOONU:
- Awe gbolohunafarahe
- Olori Awe Gbolohun
ORISII AWE GBOLOHUN AFARAHE
Orisii awe gbolohun afarahe meta ni o wa ninu ede Yoruba, awon meteeta ni: -
(a) Awe Gbolohun Afarahe Asodoruko: eyi maa n sise oro oruko ninu gbolohun. Apeere: -
Awon eniyan mo pe ounje won
Bisi daba a moto rira
Alaga feiyawo
(b) Awe Gbolohun Afarahe Asapejuwe: - Awe gbolohun yii maa n sise eyan tabi sapejuwe oro oruko ninu gbolohun. Wunren re ni “ti” ni (ami itoka won).
Apeere: -
Iresi ti mo se ko din rara.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.