LETA GBEFE KIKO : LSUS
OSE KEWAA
LETA GBEFE KIKO
AKOONU
Leta gbefe-;ni leta ti a ko si eniyan ti a mo dunju bii obi, ore ,ebi ,egbon, aburo,ara ile eni tabi eniyan miiran ti a mo ri.
Ninu leta gbefe, a le da apara tabi se efe ti o ba wu wa.
Ilana fun leta gbefe kiko
Ti a ba fe ko leta gbefe, eyi ni awon igbese ti a gbodo tele nigba ti a ba fe ko o
(i) Kiko adiresi akoleta-;eyi yoo wa ni apa otun ni oke iwe.
Muslim Grammar School,
P. O.Box 224,
Eko.
21st March 2011.
(ii) Deeti kiko-; ila ti o tele adiresi ni a maa n ko deeti si.
(iii) Ikini-;owo osi ni ibere ila ti o tele deeti ni a n.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.