OSE KESAN-ANAKAYE 1Bi a ti se mo pe asa je ihuwasi, isesi ati ibasepo awon eniyan ni agbegbe kan. Ara asa ni ounje ti a n je, aso ti a n wo, ikini, igbeyawo, isomoloruko ati iteriba fun agbalagba.Asa ijo jijo eyi ti o maa n suyo ninu tilu-tifon yala nibi ayeye isile, igbeyawo ati ikomojade tabi ni idi orisa Sango, Obatala, Orunmila ati bee bee lo se pataki. O ni bi a ti n tase agere si awon orisiirisii ilu ati orin ile Yoruba, bi a ti n repa-rese ti a si n gbe genge owo ijo si ilu bata yato gedegbe si bi a ti n gbepa-gbese si ilu dundu nidii Ogun. Eyi lo fa a ti a fi n so pe Onisango to jo ti ko tapa ta abuku ara re.Awon eegun alarinjo ni won maa n fi orin, ijo ati idan pipa da awon omo kaaro-oo-jiire lara ya laye atijo sugbon olaju ati imo ero ni aye ode-oni ti so o di ere ori-itage, ori ero asoromagbesi ati ti amohun-maworan. (NECO 2002) Ohun ti a ko ka kun asa gege bi a ti se ka a ninu ayoka yii ni (A) aso wiwo (B) igbeyawo (C) ihuwasi (D) imo ero (E)