ISEDA ORO-ORUKO : LSUS
OSE KERIN
ISEDA ORO-ORUKO
AKOONU
Oriki
Orisii Ona ti a n gba Seda Oro-Oruko
Iseda Oro-Oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi a ba fe seda oro oruko, eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.
1. Nipa lilo Afomo Ibere
Nipa lilo Afomo Aarin
Nipa sise Apetunpe kikun
Nipa sise Apetunpe Elebe
Nipa sise Akanpo Oro-Oruko
Nipa sise Isunki odidi Gbolohun.
i. Lilo Afomo Ibere
A le lo afomo ibere pelu oro-ise lati seda oro-oruko. Iru Oro-Oruko bayii gbodo ni ajose pelu oro ise ti a lo pelu afomo. Awon afomo ibere.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.