ORUNMILA : LSUS
OSE KEFA
ORUNMILA
Orunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo odun ni Ife Ondaye ki o to lo si Ado. Ibi ti o tip e julo ni ode aye. Idi niyi ti won fi n so pe ‘Ado n’ile Ifa’ Orunmila tun gbe ni Otu Ife. Ibe ni o ti bi awon omo wonyi: Alara, Ajero, Owarangun-aga, Oloyemoyin, Ontagi-Olele, Elejelu-mope ati Olowo. O tun gbe ni Ode Oyan. Ibi ti o ti bi Amukanlode-Oyan. Bakan naa ni o gbe ni ode Onko ti o ti bi Amosunlonkoegi.
IGBAGBO AWON YORUBA NIPA ORUNMILA
- Orunmila alakoso, ogbo, Imo ati Oye.
- Opitan ni Orunnmila.
- Okunrin kukuru dudu ni Orunmila
- Orunmila ni alakoso Ifa dida ati ale
- Orunmila ko ni egungun lara lati sise agbara.
- Agbaye-gborun ni Orunmila.
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.