SubjectPaid lesson
ÀKÓTÓ
CT
ClassNotes Team 3 MIN READUPDATED 27 JUN 2026ÒSÈ KETA
ÀKÓTÓ
ÀKÓÓNÚ
Àwon òrò tó ni ìró ti kò ni ìtumò.
Akótó ni sipeli titun ti àwon onimò èdè Yorùbá fi enu kò lé lórí ní odún 1974 lati ma lò.
SÍPÉLÌ ÀTIJÓ SÍPÉLÌ TITUN
-
- Aiye Ayé
- Aiya Àyà
- Eiye Eye
- Gan an Gan-an
- Enia ènìyàn
- Kini kin-ín-ní
- Okorin okunrin
- Obirin obìnrin
- Nkan nnkan
- Onje ounje
- Tani Ta ni
- Wipe wí pé
- Otta Otà
- Oshodi Osòdì
- Ogbomosho Ògbómòsó
- Iddo Ìdó
- Ottun Otun
- Shade Sadé
ÌGBÉLÉWÒN
1. Tún àwon òrò wònyí kò ni ìlànà àkótó
- Aiya
- Ofon on
- Enia
- Obirin
- Li
2. kin ni àkótó?
ÌWÉ ÀKÀTILÉWÁ
S Y Adewoyin New simplified Yoruba L1 iwe kin-in-ni Copromutt Publishers oju iwe 27-29
ÀWON EYA YORÙBÁ ÀTI IBI TÍ WÓN…