Loading...

EDE YORUBA JSS1 FIRST TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

ÀKÓRÍ ISE (EDE) ALIFABEETIA B D E E FG GB I H J KL M N O O PR S S T U W Y. ALIFABETIÌRÓ FAWEELI ÌRÓ KÓŃSONANTI Fáwéèlì Airanmupe Faweeli AranmupeA Ìró Fáweli: Ìró faweeli ni àwon ìró tí èémí won kì í ní ìdíwó nígbà tí a bá n pè wón jade láti inú èdòfóró. Orisi méjì ni ìró faweeli pín sí. Àwon náà ni: Faweeli Airanmupe; a e e i o o u Faweeli Aranmupe; an en in on un.
ORO ONISÍLÉBÙ KANBá Bé Bé Bí Bó Bó BúDá Dé Dé Dí Dó Dó DúGbá Gbé Gbé Gbí Gbó Gbó GbúJá Jé Jé Jí Jó Jó JúMá Mé Mé Mí Mó Mó MúSá Sé Sé Sí Só Só SúPá Pé Pé Pí Pó Pó PúÌGBÉLÉWÒN1 Pe àwon òrò wonyi Fá Fé Fé Fí Fó Fó Fú Gá Gé Gé Gí Gó Gó Gú Ká Ké Ké Kí Kó Kó Kú
ÀKÓTÓÀKÓÓNÚÀwon òrò tó ni ìró ti kò ni ìtumò.Akótó ni sipeli titun ti àwon onimò èdè Yorùbá fi enu kò lé lórí ní odún 1974 lati ma lò.SÍPÉLÌ ÀTIJÓ SÍPÉLÌ TITUN Aiye Ayé Aiya Àyà Eiye Eye Gan an Gan-an Enia ènìyàn
ÀKÓTÓ SÍPÉLÌ ATIJO SÍPÉLÌ TITUN Olopa olópàá Na náà Orun Òórùn Anu àànú Papa pààpàà Suru sùúrù
ONKA (1-50)1 Ookan okan2 Eeji meji3 Eeta meta4 Eerin merin5 Aarun maru-un6 Eefa mefa7 Eeje meje8 Eejo mejo9 Eesan mesan-an10 Eewaa mewaa
ONKA (51-100)Gégé bí a ti so sáájúpe 50 ni àádòta.60 máa jé ogóta,80 máa ogórin, 100 máa je ogorùn-ùn60 ogóta (ogún meta) 20*380 ogórin(ogún merin) 20*4100 ogorun-un (ogun marun) 20*5Leyin eyi a maa n ni aado, eyi si tumo si -10 Fun apeere .70 Aadorin (80-10) =70
AMI OHUÀKÓÓNÚ Ami Konsonsnti Faweeli SilebuEde Yoruba je ede ami ohun.Ami ori oro meta ni a ni ninu ede Yoruba.Awon naa niAmi ohun isale ( \ )Ami ohun aarin( )Ami ohun oke ( / )AMI OHUN ISALEBa Fa Ge GbaJe Ka Na RaAMI OHUNAARINBe Fe Ge GbeJe ki Lo Re
AMI OHUNÀKÓÓNÚ KonsonantiFaweeliGege bi a ti so saaju pe, ami ohun meta ni a ni ninu ede Yoruba. Ki a ranti pe faweeli nikan ni a maa n fi ami si lori afi konsonanti aranmupe asesilebu (m/n).Awon wonyi nikan ni won maa n gba ami sori ninu konsnantibakan naa ni won le da duro gege bi odindi silebu ninu ede Yoruba.
ORI-OROAROKO ALAPEJUWEITESIWAJU LORI AROKO ALAPEJUWEÀKÓÓNÚ BI AROKO WA SE GBODO RI SISE ILAPA ERO BI A SE N SE ILAPA EROAroko je ona ti a ngba gbe ero eni kale lori koko tabi ori oro kan fun elomiran lati gbe e yewo.Aroko alapejuwe ni aroko ti a n fi n se apejuwe nnkan tabi enikan. Bi a ba fe ko aroko, a gbodo ni imo kikun lori ohun ti a nse apejuwe re, tabi ori oro ti a ba yan. O si le je ohun ti a ni iriri nipa re.A gbodo se apejuwe yii lona ti eni ti o n ka aroko naa yoo fi le maa foju inu wo ohun ti a n sapejuwe re tabi ki o tile da nnkan naa mo bi o ba rii funra re.
AROKO ALAPEJUWE ILE IWE MIBi a ba fe ko eyikeyi aroko, agbodo fara bale daadaa,ni akoko ti a ti ri ohun ti a fe ko ko aroko le lori ohun akoko ni yiyan ori- oro, leyin igba yii ni ilapa ero, ki aroko wa le gunrege pelu ero pipe.A o gbodo fi owo kekere mu awon nnkan bi owe.akanlo ede,afiwe, akoto ode oni, ami ninu aroko. Awon nnkan wonyi dabi ki a fi iyo,magi,iru sinu obe ni. Fun apeere, e je ka wo aroko atonisona lori ile iwe mi.ILE IWE MIOruko ile iwe miAgbegbe ibi ti o waIpinle ibi ti o waOruko oga ile iwe reKin ni ohun ti a koko mma ri bi a de ibeOluko melo ni o wa ni ile iwe re

Subject Reviews:

Average Rating0
  0 Ratings
  Details
  5 Stars0%0
  4 Stars0%0
  3 Stars0%0
  2 Stars0%0
  1 Stars0%0

  No reviews yet.

  Also available in Bundles