ÀKÓTÓ ..
ÒSÈ KERIN
ÀKÓTÓ
SÍPÉLÌ ATIJO SÍPÉLÌ TITUN
Olopa olópàá
Na náà
Orun Òórùn
Anu àànú
Papa pààpàà
Suru sùúrù
Alafia àlaafia
Oloto olooto
Dada daadaa
miran miiran
Alanu alaanu
Ologbe oloogbe
Lailai laelae
ÌGBÉLÉWÒN
1 Kin ni akoto ?
2 Tun awon oro wonyi ko ni ilana akoto.
- Alafia
- Papa
- Alanu
ÌWÉ ÀKÀTILÉWÁ
1 New simplified Yoruba iwe kin-in-ni [J s s1] oju iwe 27-29 lati owo S.Y Adewoyin.
2 Eko ede ati asa Yoruba iwe kin-in-ni (J S S 1)…