AMI OHU
ÒSÈ KEJE
AMI OHU
ÀKÓÓNÚ Ami
Konsonsnti
Faweeli
Silebu
Ede Yoruba je ede ami ohun.Ami ori oro meta ni a ni ninu ede Yoruba.Awon naa ni
Ami ohun isale ( \ )
Ami ohun aarin( )
Ami ohun oke ( / )
AMI OHUN ISALE
Ba Fa Ge Gba
Je Ka Na Ra
AMI OHUNAARIN
Be Fe Ge Gbe
Je ki Lo Re
AMI OHUN OKE
Ba Fe Ge Gbe
Ji Ki Ni Ri
ÌGBÉLÉWÒN
Fi ami si ori awon oro wonyii
Ba-ba (father)
Gba-gbe (forget)
Gba-gbo (believe)
Ba-wi (punish)
Ri-ra (To buy)
ÌWÉ ÀKÀTILÉWÁ
Eko ede ati asa Yoruba iwe kin-in-ni oju…