Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

AROKO ALAPEJUWE ILE IWE MI

ClassNotes Team 3 MIN READUPDATED 29 JUN 2026

ÒSÈ KEWAA

AROKO ALAPEJUWE ILE IWE MI

Bi a ba fe ko  eyikeyi aroko, agbodo fara bale daadaa,ni akoko ti a ti ri ohun ti a fe ko ko aroko le lori ohun akoko ni yiyan ori- oro, leyin igba yii ni ilapa ero, ki aroko wa le gunrege pelu ero pipe.

A o gbodo fi owo kekere mu awon nnkan bi owe.akanlo ede,afiwe, akoto ode oni, ami ninu aroko.  Awon nnkan wonyi dabi ki a fi iyo,magi,iru sinu obe ni. Fun apeere, e je ka wo aroko atonisona lori ile iwe mi.

ILE IWE MI

Oruko ile iwe mi

Agbegbe ibi ti o wa

Ipinle ibi ti o wa

Oruko oga ile iwe re

Kin ni ohun ti a…