Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

ORI-ORO

ClassNotes Team 4 MIN READUPDATED 29 JUN 2026

ÒSÈ KESAN AN

ORI-ORO

AROKO ALAPEJUWE

ITESIWAJU LORI AROKO ALAPEJUWE

ÀKÓÓNÚ

  • BI AROKO WA SE GBODO RI
  • SISE ILAPA ERO
  • BI A SE N SE ILAPA ERO

Aroko je ona ti a ngba gbe ero eni kale lori koko tabi ori oro kan fun elomiran lati gbe e yewo.

Aroko alapejuwe ni aroko ti a n fi n se apejuwe nnkan tabi enikan.  Bi a ba fe ko aroko, a gbodo ni imo kikun lori ohun ti a nse apejuwe re, tabi ori oro ti a ba yan.  O si le je ohun ti a ni iriri nipa re.

A gbodo se apejuwe yii lona ti eni ti o n ka aroko naa yoo fi le maa foju inu wo…