GBOLOHUN ABODE
OSE KERIN
GBOLOHUN ABODE
AKOONU: Itumo gbolohun abode
Apeere gbolohun abode
Gbolohun abode ni gbolohun ti ki i ni ju eyo oro ise kan lo gege bi a ti so saaju. E je ki a se itupale irufe gbolohun yii tabi ki a so pe ki a wo tifuntedo gbolohun onibo.
Apeere
Kola ya iwe.
(Oluwa) (oro ise) (abo)
Iyawo bi omo.
(oluwa) (oro ise) (abo)
Bade pa ariwo.
(oluwa) (oro ise) (abo)
IGBELEWON
Se itupale awon gbolohun eleyo oro ise/abode.
Kunle je ewa
Tunde kan aga
Alabi ko ile.
Ewure je ewa
Ade je iyan.
IWE AKATILEWA
Oyebamji Mustapha (2009) Eko Ede Yoruba Titun oju iwe…