Loading...

EDE YORUBA JSS1 THIRD TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

Leta kiko ni ona ti a n gba ranse asiri si ara eni. Oun ni o duro fun aroko pipa lode oni. A maa n fi ero ara eni han ninu iru leta (aroko) yii. Aroko onileta nise pelu kiko sile. Leta yii pin si orisii meji awon naa ni: leta gbefe ati leta aigbefe. Leta gbefe ni leta si obi, ore, ibatan ati awon miiran ti o sun moni.
Leta aigbefe je leta ti ko gbefe rara, ti a ko si eni ti o wa ni ipo giga tabi aaye owo. O le je leta iwase, leta ifisun, leta igbaaye lenu ise, leta si ijoba ibile. Igbese meje ni a ni lati tele bi a ba fe ko leta aigbefe. Awon naa ni: Kiko adireesi akoleta. Kiko deeti ( ojo, osu ati odun ti a ko leta). Ipo ati adireesi eni ti a n ko leta si. Ikini ibere leta. Akole leta. Koko oro inu leta.
OSE KETAORO ISEAKOONU: Oro ise Ise oro ise ninu gbolohunOro ise je okan pataki lara isori oro(part of speech) Yoruba. Lara isori oro ni a ti fa oro ise (Verb) yo. Wayio, Oro ise ni oro ti o n fi isele inu gbolohun han TABI ki a so wi pe oro ise ni opomulero gbolohun. Apeere oro ise ni: lo, sun, sare, jeun, se, wa, ri, han, ropo, duro, jokoo, rerin-in, dide, korin, sunkun, wo, pade, ro, ka, pade, to, to abbl. Egan ni hee, oro ise se Pataki ninu gbolohun. Oun ni opomulero gbolohun. Apeere: Bade lo ile. Aja sun si ori aga. Kunle sare tete Alabi jeun. Bode duro jeje.
GBOLOHUN ABODEAKOONU: Itumo gbolohun abode Apeere gbolohun abodeGbolohun abode ni gbolohun ti ki i ni ju eyo oro ise kan lo gege bi a ti so saaju. E je ki a se itupale irufe gbolohun yii tabi ki a so pe ki a wo tifuntedo gbolohun onibo.Apeere Kola ya iwe. (Oluwa) (oro ise) (abo) Iyawo bi omo. (oluwa) (oro ise) (abo)
OSE KKARUN-UNORO-APONLEOro aponle ni a n lo lati yan tabi se afikun itumo fun oro ise tabi apola-ise ninu gbolohun.Ise oro-aponle ni lati se afikun itumo fun apola-ise ninu gbolohun lati mu ki itumo re yeni yekeyeke si bi apeere:Tun n rin werewere lo si ileAde n rin kanmokanmo bo.Fadeke n jenu waduwadu.Adebisi n soro fatafata ni kilaasi.Igi osan naa ga fiofio.
OSE KEFAGBOLOHUN EDE YORUBAgbolohun ni ipede ti o kun pelu itumo kikun. Orisii eya gbolohun meji ni o wa. Awon eya naa ni: (i) gbolohun ni ilana ihun ati(ii) gbolohun ni ilana ise tabi ise ti o n je. Gbolohun ni Ilana Ihun ni: gbolohun eleyo oro ise (abode), olopo oro ise (onibo) ati alakanpo. Gbolohun eleyo oro ise o maa n ni eyo oro ise kan. Apeere: ade pa eku. Gbolohun Olopo Oro-Ise: o maa n ni ju eyo oro ise kan lo. Apeere: Kunle sare tete lo pon omi Gbolohun alakanpo: o maa n gbolohun meji ninu. O si maa ni oro asopo ninu pelu. Apeere: Apeere: Olu je buredi ati eyin.
OSE KEJEONKA (101-200)Opolopo eniyan ni o ro wi pe awon alawo funfun ni o ko awon Yoruba ni onka. Ko ri be rara. Ki awon alawo funfun to de ni awon Yoruba ti n se isiro orisiirisii nnkan. Onka lati ookan titi de igba ni a fe yewo bayi. Ona meji ni a fi n se onka ninu ede Yoruba. A le so pe eni, eji tabi ki a so pe meni (mu eni), meji (mu eji) ati bee bee lo. Idi-idi ni onka Yoruba. Eyo onka Yoruba mewaa ni o wa ninu idi kookan. Eyo mewaa akoko ni o ni oruko otooto ti a n pe won. Awon ni iwonyi: 1 - ookan okan. 2 - eeji meji. 3 - eeta meta. 4 - eerin merin. 5 - aarun maru-un. 6 - eefa mefa. 7 - eeje meje.
OSE KEJOAROSO ASOTAN/ONIROYIN AKOONU: Itumo Apeere. Igbese. Aroso ni aroso iroyin ohun ti o sele ni oju wa tabi ti won so wa fun ti a n so iroyin naa fun elo miiran laisi si ayokuro tabi afikun. O ye ki eni ti yoo royin nnkan le royin finnifinni lona ti ko si nibe nigba ti isele naa sele yoo fi le fi oju inu wo nnkan naa bi igba ti oun gan alara fi oju se konge ohun naa ni. Die ninu awon ori oro ti a le ko aroso oniroyin le lori ni wonyi:- Ija igboro kan to soju mi Ijamba moto kan ti mo wa ninu re
OSE KESAN-ANORO ORUKOOro oruko (noun) ni awon oro ti o n sise Oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. ISE ORO ORUKO NINU GBOLOHUN Oluwa (Subject): Oluwa ni oluse isele inu gbolohun. Ori re ni oro ise maa n dale lori. Ibere gbolohun ni o saba maa n wa.

Subject Reviews:

Average Rating0
  0 Ratings
  Details
  5 Stars0%0
  4 Stars0%0
  3 Stars0%0
  2 Stars0%0
  1 Stars0%0

  No reviews yet.

  Also available in Bundles