Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

GBOLOHUN EDE YORUBA

ClassNotes Team 5 MIN READUPDATED 5 JUL 2026

OSE KEFA

GBOLOHUN EDE YORUBA

gbolohun ni ipede ti o kun pelu itumo kikun. Orisii eya gbolohun meji ni o wa. Awon eya naa ni: (i) gbolohun ni ilana ihun ati

(ii) gbolohun ni ilana ise tabi ise ti o n je.

  1. Gbolohun ni Ilana Ihun ni: gbolohun eleyo oro ise (abode), olopo oro ise (onibo) ati alakanpo.
  • Gbolohun eleyo oro ise o maa n ni eyo oro ise kan. Apeere: ade pa eku.
  • Gbolohun Olopo Oro-Ise: o maa n ni ju eyo oro ise kan lo. Apeere: Kunle sare tete lo pon omi
  • Gbolohun alakanpo: o maa n gbolohun meji ninu. O si maa ni oro asopo ninu pelu. Apeere: Apeere: Olu je buredi ati eyin.
  1. Gbolohun…