Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

ONKA (101-200)

ClassNotes Team 8 MIN READUPDATED 5 JUL 2026

OSE KEJE

ONKA (101-200)

Opolopo eniyan ni o ro wi pe awon alawo funfun ni o ko awon Yoruba ni onka. Ko ri be rara. Ki awon alawo funfun to de ni awon Yoruba ti n se isiro orisiirisii nnkan. Onka lati ookan titi de igba ni a fe yewo bayi. Ona meji  ni a fi n se onka ninu ede Yoruba. A le so pe eni, eji tabi ki a so pe meni (mu eni), meji (mu eji) ati bee bee lo. Idi-idi ni onka Yoruba. Eyo onka Yoruba mewaa ni o wa ninu idi kookan. Eyo mewaa akoko ni o ni oruko otooto ti a n pe won. Awon ni iwonyi:

              1  - ookan                            okan.