AKAYE
OSE KEJE
AKAYE
Akaye je okan ninu ise ti a fi n mo bi eniyan se gbo ede Yoruba to. Akekoo gbodo le ka ayoka ti a fun-un ki o si le dahun awon ibeere lori re lati fi han pe ayoka bee ye oun daadaa. Ohun ti a ka to yeni yekeyeke ni akaye. Gbogbo koko to wa ninu ni akekoo gbodo fayo, ki akekoo to le se eyi ni aseyori. O ni awon igbese kan ti akekoo gbodo gbe lori ayoka bee.
1. O gbodo koko fi pelepele ka a de le ni igba akoko
2. A tesiwaju lati ka ayoka naa leekeji lati wa awon ibi ti ibeere ti jeyo
3. Igbese to tele ni ki o…