Loading...

EDE YORUBA JSS2 FIRST TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

OSE KIN-IN-NIORI ISE: Atunyewo fonoloji ede YorubaAKOONU: Iro konsonanti Iro faweeli Iro ohunFonoloji tumo si eto bi a se n sin awon iro kookan po di oro ninu ede Yoruba. Awon iro to se pataki ninu ede Yoruba ni iro faweeli, iro konsonanti ati iro ami ohun. IRO FAWELIOna meji ni a pin iro faweli si, awon ni faweeli aranmupe ati airanmupe.
OSE KEJIEDE GBOLOHUN ONIBOAKOONU Oriki gbolohun onibo Apeere atoka/wuren gbolohun onibo Apeere gbolohunNi opo igba a maa n pe gbolohun onibo ni gbolohun olopo oro ise tabi gbolohun alakanpo.Gbolohun onibo ni eyi ti a fi gbolohun kan ha ihun omiiran. Irufe gboloun yii maa n ni ju eya kan lo. Atoka/wuren gbolohun onibo ni: ti, ki,iba,ni,pe,nigba,bi.Fun apeere. O gba ile ti mo ra E gbodo so fun mi ki e to wa A o jo lo bi e ba de
OSE KETAEDE AWE GBOLOHUNAwe gbolohun ni apakan odindi gbolohun. Awe gbolohun pin si orisii meji. Awon naa ni awe gbolohun afarahe ati olori awe gbolohun.Olori Awe Gbolohun: Olori awe gbolohun ni abala apakan odindi gbolohun ti o le da duro pelu itumo. Fun apeere. Mo ti lo ki ore mi de Gbogbo ilu gbo pe oba waja Akekoo naa mura ki o le gbebun
OSE KERINEYA AWE GBOLOHUN AFARAHEAKOONU:- Awe gbolohunafarahe Olori Awe GbolohunORISII AWE GBOLOHUN AFARAHEOrisii awe gbolohun afarahe meta ni o wa ninu ede Yoruba, awon meteeta ni: -(a) Awe Gbolohun Afarahe Asodoruko: eyi maa n sise oro oruko ninu gbolohun. Apeere: - Awon eniyan mo pe ounje won Bisi daba a moto rira Alaga feiyawo
OSE KARUN-UNONKA (100-300)Ninu onka Yoruba, a maa n lo ilana aropo (+), ayokuro (-) ati isodipupo (*). Awon ilana yii maa n waye ni gbogbo igba ti a ba n ka Yoruba. Isodipupo ogun ogun ogoji (ogun meji) ogun (ogun marun) (20*5)120 ogofa (ogun mefa) 20*6140 ogoje (ogun meje) 20*7160 ogojo (ogun mejo) 20*8180 ogosan (ogun mesan) 20*9
OSE KEFAONKA YORUBA (300-500)Gege bi a ti a so seyin pe iyato diedie yoo ba onka 20, 40, 60, ati 80 ni kete ti a kuro lori igba (200). Fun apeere:20 okoo40 oji60 ota80 orin300 ni a n pe ni oodunrun.400 je irinwo ti 500 maa je eedegbeta (600-100)=500. 600 ni a pe ni egbeta (200*3). 300 oodunrun 320 okooleloodunrun 340 ojileloodunrun 360 otaleloodunrun
OSE KEJEAKAYEAkaye je okan ninu ise ti a fi n mo bi eniyan se gbo ede Yoruba to. Akekoo gbodo le ka ayoka ti a fun-un ki o si le dahun awon ibeere lori re lati fi han pe ayoka bee ye oun daadaa. Ohun ti a ka to yeni yekeyeke ni akaye. Gbogbo koko to wa ninu ni akekoo gbodo fayo, ki akekoo to le se eyi ni aseyori. O ni awon igbese kan ti akekoo gbodo gbe lori ayoka bee.1. O gbodo koko fi pelepele ka a de le ni igba akoko2. A tesiwaju lati ka ayoka naa leekeji lati wa awon ibi ti ibeere ti jeyo3. Igbese to tele ni ki o wa maa dahun awon ibeere naa ni okookan ni oro ara re.4. Idahun re gbodo je mo ohun ti won beere lori ayoka naa
OSE KEJOITESIWAJU LORI AKAYENi aaro kutukutu ni Abeni iya Olatide kan ilekun mo o lori. O wa ba a soro lori aitete ni iyawo. Pelu omije ni Abeni fi kuro nibe. Ori ekun ni Akangbe ba ore re Olatide. O ro pe ki o ma ba okan je, ko si je ki awon jade lo si agbo faaji.Olatide binu soro ore re pe ase ore alainironu ni oun n ba rin. Gbogbo ore ti o ju pe ki a lo ile oti lo . Nko ni iyawo bee ni nko bimo kan soso se iyen o to ro. Soobu iya gbajumo oloti ni Akangbe lo. O ra igo oti nla meji pelu eran igbe meji. Laipe ti o mu eyi tan o tun ra igo oti merin si. Oti bere si pa a. O wa n fi igo oti le awon eniyan kiri Bayi ni iya oloti pe awon olopaa ti won si mu lo si ago won.
OSE KESAN-ANAKOTOAKOONU: Akoto Awon oro to ni iro ti ko ni itumo.Akoto ni sipeli titun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati ma lo.SIPELI ATIJO SIPELI TUNTUN Aiye Aye Aiya Aya Eiye Eye Gan an Gan-an Enia eniyan
OSE KEWAAAKOTO (ORISIRISI ORUKO)AKOONU: Oruko amutorunwa Oruko abiso Oruko abiku Oruko orikoOruko amutorunwa ni oruko eyi ti a n pe omo gege bi ona tabi ipo ti omo gba waye nigba ti won bi.ORUKO ITUMOTiawo/Kehinde akobi ninu awon ibeji(aburo)Kehinde omo ti a bi tele TaiwoIdowu omo ti a bi tele awon ibejiIge omo ti o ba ese wayeDada omo ti irun ori re ta kokoAjayi omo ti o da oju bole nigba ti a biOke omo ti o di ara re sinu apo felefele wayeOlugbodi omo ti ika owo re tabi ika ese re pe mefaORIKI ABISO: Awon oruko ti on toka si ipo tabi aaye ti ti awon obi omo wa nigba ti won bi omo naa.ORUKO ITUMO

Subject Reviews:

Average Rating0
  0 Ratings
  Details
  5 Stars0%0
  4 Stars0%0
  3 Stars0%0
  2 Stars0%0
  1 Stars0%0

  No reviews yet.

  Also available in Bundles