AKOTO (ORISIRISI ORUKO)
OSE KEWAA
AKOTO
ORISIRISI ORUKO
AKOONU:
- Oruko amutorunwa
- Oruko abiso
- Oruko abiku
- Oruko oriko
Oruko amutorunwa ni oruko eyi ti a n pe omo gege bi ona tabi ipo ti omo gba waye nigba ti won bi.
ORUKO ITUMO
Tiawo/Kehinde akobi ninu awon ibeji(aburo)
Kehinde omo ti a bi tele Taiwo
Idowu omo ti a bi tele awon ibeji
Ige omo ti o ba ese waye
Dada omo ti irun ori re ta koko
Ajayi omo ti o da oju bole nigba ti a bi
Oke omo ti o di ara re sinu apo felefele waye
Olugbodi omo ti ika owo re tabi ika ese re pe mefa
ORIKI ABISO: Awon oruko ti on toka si ipo tabi aaye…