SubjectPaid lesson
EDE AWE GBOLOHUN
CT
ClassNotes Team 4 MIN READUPDATED 5 JUL 2026OSE KETA
EDE AWE GBOLOHUN
Awe gbolohun ni apakan odindi gbolohun. Awe gbolohun pin si orisii meji. Awon naa ni awe gbolohun afarahe ati olori awe gbolohun.
Olori Awe Gbolohun: Olori awe gbolohun ni abala apakan odindi gbolohun ti o le da duro pelu itumo. Fun apeere.
- Mo ti lo ki ore mi de
- Gbogbo ilu gbo pe oba waja
- Akekoo naa mura ki o le gbebun
Awe Gbolohun Afarahe: Awe gbolohun afarahe je awe gbolohun ti ko le da duro pelu itumo. Omaa n fara he olori awe gbolohun ni. Fun apeere.
- Ore mi ti o lo si Eko ti de
- Mo ti lo ki ore mi to de
- Mo we nigba ti mo setan
- Awon eniyan…