EYA AWE GBOLOHUN AFARAHE
OSE KERIN
EYA AWE GBOLOHUN AFARAHE
AKOONU:
- Awe gbolohunafarahe
-
- Olori Awe Gbolohun
ORISII AWE GBOLOHUN AFARAHE
Orisii awe gbolohun afarahe meta ni o wa ninu ede Yoruba, awon meteeta ni: -
(a) Awe Gbolohun Afarahe Asodoruko: eyi maa n sise oro oruko ninu gbolohun. Apeere: -
Awon eniyan mo pe ounje won
Bisi daba a moto rira
Alaga feiyawo
(b) Awe Gbolohun Afarahe Asapejuwe: - Awe gbolohun yii maa n sise eyan tabi sapejuwe oro oruko ninu gbolohun. Wunren re ni “ti” ni (ami itoka won).
Apeere: -
Iresi ti mo se ko din rara
Iyawo mi ti o lo idale ti de
Iwo ti mo ri…