Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

ITESIWAJU LORI AKAYE

ClassNotes Team 5 MIN READUPDATED 22 JUN 2026

OSE KEJO

ITESIWAJU LORI AKAYE

Ni aaro kutukutu ni Abeni iya Olatide kan ilekun mo o lori. O wa ba a soro lori aitete ni iyawo. Pelu omije ni Abeni fi kuro nibe. Ori ekun ni Akangbe ba ore re Olatide. O ro pe ki o ma ba okan je, ko si je ki awon jade lo si agbo faaji.

Olatide binu soro ore re pe ase ore alainironu ni oun n ba rin. Gbogbo ore ti o ju pe ki a lo ile oti lo . Nko ni iyawo bee ni nko bimo kan soso se iyen o to ro. Soobu iya gbajumo oloti ni Akangbe lo. O ra igo oti nla meji pelu eran igbe meji. Laipe ti…