SubjectPaid lesson
APOLA-ISE (verb phrase)
CT
ClassNotes Team 4 MIN READUPDATED 5 JUL 2026OSE KETA
APOLA-ISE
(verb phrase)
Ninu apola-ise ni koko gbolohun maa n wa. orisiirisii isori oro ni o le jeyo po ninu apola-ise. Apola-ise le je:
- Oro-Ise Alaigbabo.
Iji ja
Mo sun
Iyan naa kan
- Oro-ise ati oro-oruko ni ipo abo. Apeere:
Dolapo ra keke
Mo je akara.
Femi pari idanwo
- Oro-Ise agbabo ati Eyan. (oro aponle). Apeere:
Bola mu oti yo.
Jide gun igi giga fiofio.
Mo rerin-in arintakiti.
- Oro-Ise ati Apola Atokun apeere:
Bola lo si Obilende ni ana.
Mo ti ilekun si ita.
- Eyo Oro-Ise ti o n sise odidi gbolohun. Apeere:
Jade
Jokoo
Dide
IGBELEWON
- Ko apeere Apola-Ise marun-un sile pelu apeere metameta yato si eyi ti o wa…