Loading...

EDE YORUBA JSS2 THIRD TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

Leta kiko ni ona ti a n gba ranse asiri si ara eni. Oun ni o duro fun aroko pipa ranse lode oni. A maa n fi ero ara eni han ninu iru leta (aroko) yii. Leta pin si orisii meji awon naa ni: leta gbefe ati leta aigbefe. Leta gbefe ni leta si obi,ore, ibatan ati awon miiran ti o sun moni. Ilana leta gbefe ni: adiresi, deeti, ikini ibere, koko aroko, ikini ipari.
OSE KEJIAPOLA ORUKO (Phrases)Apola ni apa kan gbolohun ti o le je oro tabi akojopo oro. Lara apola inu ede Yoruba ni apola oruko, aopla ise, ati apola aponle.Apola Oruko (noun phrase): okan ninu apola oro ti a hun po di gbolohun ni apola oruko. Apola Oruko le je: Oro Oruko eyo kan ni ipo oluwa tabi ni ipo abo. Apeere;Yetunde sun fonfonEpo wa ni Sapele. Oro Oruko tabi Akojopo Oro Oruko ti o n sise eyan. Apeere:
OSE KETAAPOLA-ISE(verb phrase)Ninu apola-ise ni koko gbolohun maa n wa. orisiirisii isori oro ni o le jeyo po ninu apola-ise. Apola-ise le je: Oro-Ise Alaigbabo.Iji jaMo sunIyan naa kan Oro-ise ati oro-oruko ni ipo abo. Apeere:Dolapo ra keke
OSE KERINEDEISEDA ORO ORUKO AKOONU:- __ Afomo ibere Afomo aarin NOOTIOrisiirisii igbese ni a le gbe lati seda oro oruko yato si awon oro oruko ponbele ti a ni ninu ede Yoruba, sugbon ise kan naa ni gbogbo won n se ninu gbolohun.AFOMO IBERE(A) A maa n seda oro oruko nipa fifi afomo ibere mo oro ise kan. Awon wunren afomo ibere ni:- a e e i o o a e i o o
OSE KARUN-UNEDEISEDA ORO ORUKOAPETUNPE (a) Igba, asiko ati onka ni awon oro oruko ti a n seda bayii maa n ba lo ju. Apeere:- Osu + osu = osoosun Odun + Odun = Odoodun Orun + Orun = Oroorun Egbe + egbe = Egbeegbe Mejo + mejo = Mejeejo
OSE KEFAEDELETA AIGBEFEAkoonu: Leta aigbefe Igbese kiko leta aigbefe Leta aigbefe je leta ti ko gbefe rara, ti a n ko si eni ti o wa ni ipo tabi aaye owo. O le je leta iwase, leta ifisun, leta igbaaye lenu ise, leta si ijoba ibile. Igbese meje ni a ni lati tele bi a ba fe ko leta aigbefe. Awon naa ni: Kiko adireesi akoleta Kiko deeti ( ojo, osu ati odun ti a ko leta) Ipo ati adireesi eni ti a ko leta si Ikini ibere leta Akole leta
OSE KEJEEDEAMI OHUN ONISILEBU MEJI(fi ara bale daadaa pe awon oro wonyi pelu ami ori won)AMI OKE AMI ISALE AMI AARIN sibi iji ife Kunle igba omo Wale ego ire
OSE KEJOEDEATUNYEWO AWON AWE GBOLOHUNAwe gbolohun ni apakan odindi gbolohun. Awe gbolohun pin si orisi meji. Awon naa ni awe gbolohun afrahe ati olori awe gbolohun.Olori Awe Gbolohun: Olori awe gbolohun ni abala apakan odindi gbolohun ti o le da duro pelu itumo.Fun apeere. Mo ti lo ki ore mi de Gbogbo ilu gbo pe oba waja Akekoo naa mura ki o le gbebunAwe Gbolohun Afarahe: Awe gbolohun afarahe je awe gbolohun ti ko le da duro pelu itumo. Omaa n fara he olori awe gbolohun ni. Fun apeere. Ore mi ti o lo si Eko ti de. Mo ti lo ki ore mi to de.
OSE KESA-ANEDEAPOLA APONLEOro aponle ni awon oro tabi akojopo oro to n sise aponle fun oro ise. Apeere oro aponle ni daradara, kiakia, foo. Orisiirisii oro aponle ti ani ninu ede Yoruba ni: apola aponle oniba, apola aponle alasiko, apola aponle onibi, apola aponle onidii, apola aponle alafiwe.Apola Aponle Oniba: Apola aponle yii maa n toka si isesi, iba tabi bi a se n se nnkan ninu gbolohun. A le lo wuren ibeere *Bawo ni* fun irufe awon gbolohun wonnyi. Fun apeere: Pupa foo Tutu nini Ga fiofio Ara baba naa ya diedie

Subject Reviews:

Average Rating0
  0 Ratings
  Details
  5 Stars0%0
  4 Stars0%0
  3 Stars0%0
  2 Stars0%0
  1 Stars0%0

  No reviews yet.

  Also available in Bundles