SubjectPaid lesson
EDE ATUNYEWO AWON AWE GBOLOHUN
CT
ClassNotes Team 6 MIN READUPDATED 30 JUN 2026OSE KEJO
EDE
ATUNYEWO AWON AWE GBOLOHUN
Awe gbolohun ni apakan odindi gbolohun. Awe gbolohun pin si orisi meji. Awon naa ni awe gbolohun afrahe ati olori awe gbolohun.
Olori Awe Gbolohun: Olori awe gbolohun ni abala apakan odindi gbolohun ti o le da duro pelu itumo.Fun apeere.
- Mo ti lo ki ore mi de
- Gbogbo ilu gbo pe oba waja
- Akekoo naa mura ki o le gbebun
Awe Gbolohun Afarahe: Awe gbolohun afarahe je awe gbolohun ti ko le da duro pelu itumo. Omaa n fara he olori awe gbolohun ni. Fun apeere.
- Ore mi ti o lo si Eko ti de.
- Mo ti lo ki ore mi to de.
- Mo we nigba ti mo setan
- Awon…