EDE LETA GBEFE : LSUS

OSE KIN-IN-NI

EDE

LETA GBEFE

AKOONU: Leta

                 Adiresi

                 Deeti

                Ikini ibere

                Koko oro

                Asokagba

                Ikini ipari

Leta kiko ni ona ti a n gba ranse asiri si ara eni. Oun ni o duro fun aroko pipa ranse lode oni. A maa n fi ero ara eni han ninu iru leta (aroko) yii. Leta  pin si orisii meji awon naa ni: leta gbefe ati leta aigbefe. Leta gbefe ni leta si obi,ore, ibatan ati awon miiran ti o sun moni. Ilana leta gbefe ni: adiresi, deeti, ikini ibere, koko aroko, ikini ipari.

          Kiko  adireesi: oke apa otun ni a maa n ko adiresi eni ti o n ko leta si. Adiresi yii maa n ni awon nnkan wonyi ninu: nomba, adugbo,opopona, ipinle. Fun apeere:

View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.