AKORI ISE (EDE): AROKO ALARIYANJIYAN
OSE KEFA
AKORI ISE (EDE): AROKO ALARIYANJIYAN
AKOONU: Itumo aroko alariyanjiyan.
Apeere aroko alarinyanjiyan.
Aroko alariyanjiyan je aroko ti a ti maa n jiyan lori nnkan kan. Ninu aroko yii alaroko gbodo maa ko si otun ati osi. Iyen ni pe alaroko gbodo maa ko aroko lori ero meji. Fun apeere aroko lori obinrin dara ninu ise ile ju okunrin lo. Ti a ba fe ko aroko bayi, a gbodo ko lori idi ti obinrin fi dara ninu ise ile bakan naa ni a gbodo ko lori pe okunrin naa dara ninu ise ile. A o ko aroko yii ti eni ti o n ka aroko naa o ni mo ero wa denudenu. Ayafi ti o ba…