Loading...

EDE YORUBA JSS3 FIRST TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

OSE KIN-IN-NI AKORI ISE (EDE): IRO PIPAJE AKOONU:- Iro pipaje Konsonanti pipaje Faweeli pipaje Iro pipaje ni dindin iye iro ti a pe ku nigba ti a ba n soro. A le pa iro konsonanti je be e naa ni a le pa iro faweeli je. Iro knosonanti pipaje ni dindin iye iro knosonanti ku nigba ti a ba n soro nigba ti iro faweeli pipaje maa je dindin iye iro faweeli ku ti a ba n soro. Iro pipaje yii wopo ninu eka ede Oyo. Awon iro ti a sakiyesi pe won saba maa n paje ju ni: r, w,y,’h,l ati k. Apeere iro “r”
OSE KEJIAROKO ALALAYE AKOONU: Aroko Alalaye Ilapa eroAroko alalaye ni a fi n se ekunrere alaye lori ori-oro kan ti eni ti o ba ka aroko bee kofi ni ni isoro lati mo ohun ti alaye wa da le lori.Apeere ori oro aroko alalaye ni : Ise ti mo fe se lojo iwaju Igba erun Eba tite Ise tisa Eran osin
OSE KETAAPOLAAKOONU: - Ki ni a n pe ni apola Ki ni apola oro oruko Ise ti apola oro oruko n se ninu gbolohun Ki ni a n pe ni apola ise Ise ti apola ise n se ninu gbolohunApola ni akojopo oro ti o n di apa kan gbolohun. Apola le je eyo oro kan, o si le je meji tabi ju bee lo. Orisiri apola lo maa n di apa kan tabi odidi gbolohun.Apola oro oruko ni eyo oro oruko kan tabi meji tabi ju bee lo ti o di apa kan odindi. O si le je apapo oro oruko ati oro oruko eyan ninu gbolohun Yoruba. Apola oro oruko le je oro oruko, oro aropo oruko, tabi aropo afara joruko.Apeere apola to je eyo oro oruko kan
OSE KERINAKORI ORO: - EYA GBOLOHUN EDE YORUBA AKOONU: -- Gbolohun eleyo oro ise - Gbolohun olopo oro ise - Gbolohun alakanpo - Gbolohun ase - Gbolohun ibeere Gbolohun ni ipede ti o kun. Ninu gbolohun, a maa n ri orisirisi isori oro paapaa julo oro ise gege bi opomulero gbolohun. Orisirisi ona ni a le pin gbolohun ede Yoruba si, Awon ni: gbolohun eleyo oro ise, olopo oro ise, gbolohun alakanpo,gbolohunase, gbolohun ibeere abbl.
OSE KARUN-UN GBOLOHUN IBEERE:- Gbolohun ibeere ni gbolohun ti a fi maa n se iwadi nnkan. Wuren gbolohun ibeere ni: da, nko, n je, ta, tai ni, Bawo, se, ki Apeere. Ki ni oruko re? Iwe yen da?
OSE KEFAAKORI ISE (EDE): AROKO ALARIYANJIYAN AKOONU: Itumo aroko alariyanjiyan. Apeere aroko alarinyanjiyan.Aroko alariyanjiyan je aroko ti a ti maa n jiyan lori nnkan kan. Ninu aroko yii alaroko gbodo maa ko si otun ati osi. Iyen ni pe alaroko gbodo maa ko aroko lori ero meji. Fun apeere aroko lori obinrin dara ninu ise ile ju okunrin lo. Ti a ba fe ko aroko bayi, a gbodo ko lori idi ti obinrin fi dara ninu ise ile bakan naa ni a gbodo ko lori pe okunrin naa dara ninu ise ile.
OSE KEJE IBASEPO LAARIN AWE GBOLOHUN ATI ODINDI GBOLOHUNGbolohun ni ipede ti o kun pelu ituno nigba ti awe gbolohun je apa kan odindi gbolhun Ara odindi gbolhun ni a ti fa awe gbolohun yo. Awe gbolohun pin si ona meji. Olori awe gbolohun ati awe gbolohun afaraheGbolohun ni ipede ti o kun ti o si loorin. Ero ati itumo gbolohun maa n kun Fun apeere
OSE KESAN-ANEYA AWE GBOLOHUN Gege bi a so saaju pe awe gbolohun pin si meji: olori awe gbolohun ati awe gbolohun afahe.1 OLORI AWE GBOLOHUN Olori awe gbolohun ni gbolohun to le da duro pelu itumo.Fun apeere. Bola jeun ni ori tabili Sade ra aso ti ko ni iho lara
OSE KEJOAKORI ISE: - Eya awe gbolohun Yoruba AKOONU: - Olori awe gbolohun Awe gbolohun afara he Gbolohun Yoruba to kun maa n ni itumo kan, o si maa n ni ise kan pato to n je. Ohun ti a mo si awe gbolohun ni tire je apa kan odidi gbolohun. Ara odidi gbolohun ni a ti fa awe gbolohun yo. Orisi awe gbolohun meji Pataki ni a le fa yo ninu ihun gbolohun .
OSE KEWAAORISIi EYA AWE GBOLOHUN AFARAHE ASAPONLE (a) Awe gbolohun afarahe asaponle alafiwe gbolohun yii maa n se afiwe nnkan meji wunren “bi” tabi “bi” ni atoka re Ade nkorin bi eye se nkorin Omo naa kigbe bi eni ti agbon ta

Subject Reviews:

Average Rating0
  0 Ratings
  Details
  5 Stars0%0
  4 Stars0%0
  3 Stars0%0
  2 Stars0%0
  1 Stars0%0

  No reviews yet.

  Also available in Bundles