IBASEPO LAARIN AWE GBOLOHUN ATI ODINDI GBOLOHUN
OSE KEJE
IBASEPO LAARIN AWE GBOLOHUN ATI ODINDI GBOLOHUN
Gbolohun ni ipede ti o kun pelu ituno nigba ti awe gbolohun je apa kan odindi gbolhun Ara odindi gbolhun ni a ti fa awe gbolohun yo. Awe gbolohun pin si ona meji. Olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe
Gbolohun ni ipede ti o kun ti o si loorin. Ero ati itumo gbolohun maa n kun Fun apeere
Mo gbo pe o ti wa mi wale
Apa kan odindi gbolohun ni awe gbolohun. Fun apeere:
Mo gbo pe o ti wa mi wale Eyi ti a fala si nidi ni a pe ni awe gbolohun afarahe. Nitori naa a maa n fa awe gbolohun yo ninu odindi…