ORISIi EYA AWE GBOLOHUN AFARAHE ASAPONLE
OSE KEWAA
ORISIi EYA AWE GBOLOHUN AFARAHE ASAPONLE
(a) Awe gbolohun afarahe asaponle alafiwe gbolohun yii maa n se afiwe nnkan meji wunren “bi” tabi “bi” ni atoka re
Ade nkorin bi eye se nkorin
Omo naa kigbe bi eni ti agbon ta
(b) Awe gbolohun afarahe asaponle alasiko eyi maa n toka asiko ti nnkan sele ninu gbolohun tabi igba. Apeere: -
Baba maa wa nigba ti o ba de
Mo ri tade ni ale ana
Bo se n bo lati ile lo ti raa dani
(d) Awe gbolohun afarahe asaponle onibi: -
A maa n fi eleyi toka ibi ti isele inu gbolohun ti waye. Apeere:
Mo ba ore mi …