AROKO ASARIYANJIYAN
OSE KEJO
AROKO ASARIYANJIYAN
AKOONU : -
Iha meji ni aroko alarinyanjiyan gbodo ni,iha beeni ati iha beeko.Iha eyi ti a faramo ati eyi ti a ko faramo.Eyi ni wi pe akekoo yoo gbenuso fun egbe kin-in-ni ti o faramo,oun kan naa ni yoo se atako fun eyi ti ko faramo.
Akekoo gbodo soro lori egbe mejeeji bi o tile je pe yoo fi si ibi kan ju ibi kan lo.Akekoo koko gbodo soro lori egbe ti ko faramo lori awon ohu n ti o dara ti o wa nibe,yoo wa soro lekunrere lori iha ti o faramo gbogbo awon ohun ti o ba so nibi ni yoo fibi ohun ti o wa ninu koko eyi ti ko faramo…