Loading...

EDE YORUBA SSS1 THIRD TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

OSE KINNIORO- ORUKO - oriki- orisiirisii oro oruko.- ise ti oro oruko n se ninu gbolohun.- lilo oro oruko ninu gbolohun. Oro –oruko ni awon oro ti won le da duro nipo oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. AP. Baba ko ebe. Tolu fo aso. Mama se isu ewura.EYA ORO ORUKO. ORUKO ENIYAN : -Oro oruko le je oruko eniyan, eyi ni oruko ti o n toka si ohun ti o je eniyan. Ap-Rotimi - Dele -Ahmed - Dokita
OSE KEJIORO AROPO ORUKO. Oriki Abuda oro aropo oruko Ate oro aropo oruko Irisi oro aropo oruko.AKOONUOro aropo oruko ni a maa n lo dipo oro-oruko ninu apola oruko.apeere ‘Bolu je akara. ‘O je e.’ ‘ewure je agbado Bola’ ‘ewure je agbado re.Abuda oro aropo oruko.1. Oro aropo oruko ni eto to n toka si iye bi eyo tabi opo.apeereO lo [ eyo ni o ]Won wa [ opo ni won] oro aropo oruko ni eto to n toka si eni.apeere. enikinni /eyi ni eni ti o n soro. Enikeji / eyi ni eni ti a n soro sii.
OSE KETAORO ISE. -Oriki Iwulo oro ise Ona ti a le gba lati da oro ise mo. Isori oro ise.```AKOONU: -Oro-ise ni oro ti o ba le duro bii koko fonran ninu gbolohunoro-ise ni oro ti o n toka si ohun ti oluwa se ninu gbolohun laisi oro ise ninu gbolohun ko le ni itunmo nitori ohun ni o je opomulero fun gbolohun.Ap. Baba ra bata. Olu fo aso.Bi a ba yo oro-ise kuro ninu awon gbolohun wonyii ko le ni itunmo.ONA TI A FI LE DA ORO-ISE MO. Oro-ise ni o maa n jeyo leyin oluwa .ap ‘mo je eba.’ won gba owo’.
OSE KERINONKA YORUBAOOKAN DE EGBAA ONA MEJI PATAKI NI ONKA YORUBA PIN SINONKAYE (ON – KA – IYE)ONKAPO (ON – KA – IPO)‘m’ ni a fi n da pupo ninu awon onkaye Yoruba mo nigba ti a n fi (i) mo onkapoApeereONKAYE ONKAPOMeni (mu eni) = 1 Ikini (iko eni) = 1stMeji (mu eji) = 2 Ikeji (iko eji) = 2ndMeta (mu eta) = 3 Iketa (iko eta) = 3rdMerin (mu erin) = 4 Ikerin (iko erin) = 4th Marun-un (mu aarun = 5 Ikarun-un (iko arun) = 5th
OSE KARUN-UNAROKO AJEMO ISIPAYAAroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Apeere aroko ajemo-isipaya ni: Ise Tisa Oge Seise. Aso Ebi Imototo. Ise ti mo fe lojo iwaju.Ki a to le ko akoyawo lori okookan ori-oro wonyi, a gbodo ni arojnle ohun ti won je, itumo ati itumo won miiran to farasin tabi ohun ti o ni abuda won. A nila ti wo anfaani ati aleebu ki a si fi arojinle ero gbe won kale.
OSE KEFAORO AROPO AFARAJORUKOOriki Abuda oro aropo afarajoruko Irisi oro aropo afarajoruko. AKOONU: -Oro aropo-afarajoruko ni isesi to frajo ti oro-oruko sugbon o mu eto iye ati eni lara abuda oro aropo oruko.Awon oro aropo afarajoruko ni wonyii; - emi,iwo,oun,awa,eyin, awon.fun apeere.Emi ko ri Bola.Ile awa dun.Abuda oro aropo afarajoruko.i. Oro aropo afarajoruko ni eto iye ati eni.Ate oro aropo afarajoruko.
OSE KEJEGBOLOHUN ONIPONNA ITUPALE GBOLOHUN ONIPONNA. Oriki Ibi ti o ti n jeyo. Apeere/itupale oro-oniponna ninu gbolohun.AKOONU: -Gbolohun oniponna-; ni gbolohun ti o ni ju itumo kan lo.gbolohun oniponna le je eyo oro tabi apola kan ni o maa ni ponna.Itupale eyo oro oniponna ninu gbolohun. Ayo ko le da mi. o tumo si pe . Ayo ko le da mi [ se eda mi ]. Ayo ko le segun mi. Isu rira ni Badejo gbin.Tumo si-
OSE KEJOAROKO ASARIYANJIYAN AKOONU : -Iha meji ni aroko alarinyanjiyan gbodo ni,iha beeni ati iha beeko.Iha eyi ti a faramo ati eyi ti a ko faramo.Eyi ni wi pe akekoo yoo gbenuso fun egbe kin-in-ni ti o faramo,oun kan naa ni yoo se atako fun eyi ti ko faramo.Akekoo gbodo soro lori egbe mejeeji bi o tile je pe yoo fi si ibi kan ju ibi kan lo.Akekoo koko gbodo soro lori egbe ti ko faramo lori awon ohu n ti o dara ti o wa nibe,yoo wa soro lekunrere lori iha ti o faramo gbogbo awon ohun ti o ba so nibi ni yoo fibi ohun ti o wa ninu koko eyi ti ko faramo subu,ibi ni yoo ti fi idi iha ti o yan mule.Akekoo gbodo fi idi iha ti o yan mule ninu igunle aroko re.A ko gbodo so itan tabi pa aalo ninu iru aroko bayii.
OSE KESAN-ANAKAYE 1Bi a ti se mo pe asa je ihuwasi, isesi ati ibasepo awon eniyan ni agbegbe kan. Ara asa ni ounje ti a n je, aso ti a n wo, ikini, igbeyawo, isomoloruko ati iteriba fun agbalagba.Asa ijo jijo eyi ti o maa n suyo ninu tilu-tifon yala nibi ayeye isile, igbeyawo ati ikomojade tabi ni idi orisa Sango, Obatala, Orunmila ati bee bee lo se pataki. O ni bi a ti n tase agere si awon orisiirisii ilu ati orin ile Yoruba, bi a ti n repa-rese ti a si n gbe genge owo ijo si ilu bata yato gedegbe si bi a ti n gbepa-gbese si ilu dundu nidii Ogun. Eyi lo fa a ti a fi n so pe Onisango to jo ti ko tapa ta abuku ara re.Awon eegun alarinjo ni won maa n fi orin, ijo ati idan pipa da awon omo kaaro-oo-jiire lara ya laye atijo sugbon olaju ati imo ero ni aye ode-oni ti so o di ere ori-itage, ori ero asoromagbesi ati ti amohun-maworan. (NECO 2002) Ohun ti a ko ka kun asa gege bi a ti se ka a ninu ayoka yii ni (A) aso wiwo (B) igbeyawo (C) ihuwasi (D) imo ero (E)
OSE KEWAALETA GBEFE KIKOAKOONULeta gbefe-;ni leta ti a ko si eniyan ti a mo dunju bii obi, ore ,ebi ,egbon, aburo,ara ile eni tabi eniyan miiran ti a mo ri.Ninu leta gbefe, a le da apara tabi se efe ti o ba wu wa.Ilana fun leta gbefe kikoTi a ba fe ko leta gbefe, eyi ni awon igbese ti a gbodo tele nigba ti a ba fe ko o (i) Kiko adiresi akoleta-;eyi yoo wa ni apa otun ni oke iwe. Muslim Grammar School, P. O.Box 224, Eko. 21st March 2011.(ii) Deeti kiko-; ila ti o tele adiresi ni a maa n ko deeti si.

Subject Reviews:

Average Rating0
  0 Ratings
  Details
  5 Stars0%0
  4 Stars0%0
  3 Stars0%0
  2 Stars0%0
  1 Stars0%0

  No reviews yet.

  Also available in Bundles