ORO AROPO ORUKO.
OSE KEJI
ORO AROPO ORUKO.
- Oriki
- Abuda oro aropo oruko
- Ate oro aropo oruko
- Irisi oro aropo oruko.
AKOONU
Oro aropo oruko ni a maa n lo dipo oro-oruko ninu apola oruko.apeere
‘Bolu je akara.
‘O je e.’
‘ewure je agbado Bola’
‘ewure je agbado re.
Abuda oro aropo oruko.
1. Oro aropo oruko ni eto to n toka si iye bi eyo tabi opo.apeere
O lo [ eyo ni o ]
Won wa [ opo ni won]
- oro aropo oruko ni eto to n toka si eni.apeere.
enikinni /eyi ni eni ti o n soro.
Enikeji / eyi ni eni ti a n soro sii.
Eniketa / eyi ni eni tabi ohun ti a n soro re.
Mo ko leta.
O ko leta
O ko leta.
3. Oro aropo oruko ni eto ipin si ipo.
IYE Eyo opo
Enikin-in-ni mo a
Enikeji o e
Eniketa o won.
4. A ko le fi oro-asopo so oro aropo oruko meji papo.apeere
mo ati o
wa ati won.
5. A ko le lo oro aropo oruko pelu da ati nko,ni,ko.apeere
mo n ko?
E da?
O ko?
6. A ko le lo eyan pelu oro aropo oruko.apeere
mo naa
e gan-an
IRISI ORO AROPO – ORUKO.
Ona meta Pataki ni a le gba lo oro aropo oruko ninu gbolohun.
- O le sise oluwa
- Abo
- Eyan ninu gbolohun.
Ipo oluwa; - oro aropo oruko maa n sise oluwa ninu gbolohun,
IYE EYO OPO.
Enikin-ni mo a
Enikeji o e
Eniketa o won
Apeere;- mo n jo
O n jo
Won n jo
E n jo
A n jo.
Ipo abo : - oro aropo oruko maa n sise abo bakan naa ninu gbolohun.
Iye Eyo Opo.
Enikin-in mi wa
Enikeji o/e yin
Eniketa faweli won
Oro-ise.
Baba na mi.
Bolu n pe o/e
Oluko pe e.
Oba ri wa.
o eyan : -oro aropo oruko maa n ni ipo eyan ninu gbolohun.
IYE EYO OPO.
Enikin-ni mi wa
Enikeji re/e yin
Eniketa re/e won.
Apeere; -
Aja mi
Aja re
Aja re
Ile wa
Aso yin
Aja won.
IGBELEWON.
- Kin ni oro aropo oruko?
- salaye awon oro aropo oruko pelu apeere.
ASA
IPOLOWO OJA
Ipolowo oja
IWE AKATILEWA
Adewoyin S.Y (2014) Imo, Ede, Asa Ati Litireso fun ile Sekondiri Agba S.S.S. 2 Corpromutt Publihers Nig Ltd Oju iwe 101-119.
LITIRESO
SISE ATUPALE EWI KEJI NINU IWE TI IJOBA YAN.
Iya Atata: Fadiya, O. (WAEC).
APAPO IGBELEWON.
- Kin ni oro aropo oruko?
- salaye awon oro aropo oruko pelu apeere.
- Ko abuda oro aropo oruko marun-un sile.
- Ko apeere aka nlo ede ayaworan mefa sile.
ISE AMURELE.
- ------- ni o maa n dipo oro oruko ninu gbolohun. [a] oro oruko [b] oro ise [d] oro aropo oruko.
- Orisii ona meta ti a le ri oro aropo oruko ni --------- [a] ipo eyan,oluwa,abo. [b] apejuwe abo,oro oruko [d] aponle,apejuwe,eya.
- Baba pe mi. Abo inu gbolohun yii ni ------- [a] baba [b] pe [d] mi.
- ‘E’ je oro aropo oruko -------- [a] enikin-ni eyo opo,[b] enikeji eyo [d] enikeji opo.
- ..... ni agunmu owo. (a) ipolowo oja (b) ate (d) awin.
APA KEJI.
- Ko ona ti won ngba polowo oja ni aye atijo marun-un.
- Ko ona ti won ngba polowo oja ni aye ode oni marun-un
- Polowo awon nnkan yii: gari, oole, eja.
- Ko abuda oro aropo oruko marun-un sile
- Salaye akanlo ayaworan merin.